Categories
Yoruba

Àwọn Àfọ̀njá, Ọ̀dàlẹ̀, Ìkà, Agbẹ̀hìnbẹbọjẹ́ Fẹ̀ Da Àmọ̀tẹ́kùn Rú Lati Ọwọ Bámidélé Adémólá-Ọlátẹ́jú

Nígbà tí wọ́n dá agbófinró Hisbah sílẹ̀ ní Òkè Ọya, ǹjẹ́ ẹ gbọ́ kí àwọn ènìyàn wọn pariwo? Ǹjẹ́ ẹ gbọ́ kí ọmọ wọn nínú Ọlọpa tàbí nínú Ọmọ Ogun Naijiria gbìmọ̀ láti dàárú? Àwọn agbẹ̀hìnbẹbọjẹ́ ilẹ̀ Yorùbá ti bẹ̀rẹ̀. Wọ́n tí ń pète-pèrò láti gbógun ti àwọn Gómìnà wá lórí ìdásílẹ̀ Àmọ̀tẹ́kùn. Ẹ wá […]